BBC News, Yorùbá - Ìròyìn
Ìròyìn tó ṣe kókó
Wọn tí sọ Nàìjíríà di Zimbabwe: Alága ẹgbẹ́ NLC figbe ta
Aarẹ ẹgbẹ oṣiṣẹ sọ pe inira to n deba araalu kọja afarada tori naa lawọn fi ṣe iwọde ifẹhonuhan.
Rògbòdìyàn bẹ́ sílẹ̀ lásìkò tí Seyi Makinde yọjú síbi ìfẹ̀hónúhàn ẹgbẹ́ òṣìṣẹ́ ní Ibadan
Awọn oluwde kọkọ yari pe awọn ko fẹ gbọ ọrọ lẹnu Gomina Makinde tori pe wọn lo wa lara awọn to ba Naijiria debi to de lonii yi.
Ṣé lóòtọ́ ni Pasuma fẹ́ ṣe ìgbéyàwó lọ́dun yìí?
Lasiko ifọrọwerọ naa, Iyabo Ojo bere pe nigba wo lo n gbero lati se igbeyawo.
Ohun méje tó yẹ kí o mọ̀ nípa àbájáde ìgbìmọ̀ Oronsaye àti bí ó ṣe kàn ọ́
Minisita fọrọ eto iroyin and ilanilọyẹ, Mohammed Idris naa si jẹ ko di mimọ fun awọn akọroyin Aso-Rock niluu Abuja.
NÍ YÀJÓYÀJÓ , Iléeṣẹ́ ọlọ́pàá ṣèlérí ààbò tó péye fáwọn tó fẹ́ kópa nínú ìfẹ̀hónúhàn ṣùgbọ́n...
Alukoro ọlọpaa Muyiwa Adejobi sọ pe ẹni ba tasẹ agẹrẹ pẹlu iwọde naa yoo foju wina ofin.
''N25,000 owó LAPO ni mo fi bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ 'Cake' ṣíṣe, àmọ, mò ń pa N70,000 lójúmọ̀ báyìí''
Tosin Ibiwoye to ti bẹrẹ iṣẹ yii fun bii ogun ọdun ṣalaye pa ọpọlọpọ eeyan ni oun ti kọ ni iṣẹ ọhun.
Tinubu kò lè pidán tí yóò mú àyípadà rere bá ètò ọrọ̀ ajé Nàìjíríà lásìkò yìí - Wòlíì Ayọdele
Gbajugbaja Wolii Ayọdele lo sọrọ yii ninu atẹjade ti akọwe iroyin rẹ, Ọṣhọ Oluwatosin fi sita laipẹ yii, to si tun ṣalaye pe nnkan yoo tubọ maa buru sii bi ijọba ba kọ lati ṣe ohun to yẹ lasiko.
“Lẹ́yìn ọdún méjì tí ogun lé mi kúrò ní Ukraine, mo ṣetán láti padà síbẹ̀ fún ìtẹ̀síwájú ẹ̀kọ́ mi”
Ṣaaju ogun, ẹgbẹrun mẹrindinlogun akẹkọọ lati Afrika lo n kawe ni Ukraine kaakiri orilẹ-ede naa.
Tinubu yan Dangote, Elemelu, Soludo sí ìgbìmọ̀ tí yóò ṣe àtúnṣe ètò ọrọ̀ ajé Nàìjíríà
Igbimọ naa lo kun fun awọn aṣoju latio ijọba apapọ, ipinlẹ ati awọn ileeṣẹ aladani ti wọn peju sibi ipade to waye nile ijọba, Aso Rock l’Abuja.
Tinubu ṣetán àmúlò àbájáde ìgbìmọ̀ Oronsanye tó dàbá àtúntò ìṣàkóso ìjọba
Ọdun 2012 ni igbimọ Oronsanye ṣe agbekalẹ aba lori ọna ti ijọba le fi mu atunto ba ẹka ileeṣẹ ijọba ati awọn ajọ labẹ ijọba.
Ìfẹ́ tó sọnu nilẹ̀ Yorùbá ló mú kí wàhálà pọ̀ lorílẹ̀èdèNàìjíría-Ooni Ife
Ọdọọdun ni ayẹyẹyi maa n waye ni Ile Ife nibi ti awọn araalu ti n pejọ lati wa kopa.
Ẹgbẹ́ oníṣèṣe gbé Emir Ilorin àti ọlọ́pàá lọ ilé-ẹjọ́ lórí bí wọ́n ṣe dá àjọ̀dún wọn dúró
Gẹgẹ bi ọkan lara awọn agbẹjọro onisẹse naa, Lọya Femisi, sọ pe ajọ ọlọpaa ni kawọn oniṣẹṣe gbe ọdun wọn kuro ni Ilọrin, o ni wọn fi ẹtọ wọn dun wọn.
Ìròyìn Àkàgbádùn
Wo ọ̀nà tí obìnrin bá gbà ní Ààfin Deji Akure tí irú obìnrin bẹ́ẹ̀ kò ní r'ọ́mọ bí láyé
Oloye Sele ti ilẹ Akure, Taiwo Fagite sọ fun BBC pe eewọ ni fun obinrin lati gba ọna yii.
Ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin l'Abuja pàṣẹ ìdádúró òfin tí NAFDAC fi de ọtí pẹlẹbẹ inú ọ̀rá
Ninu atẹjade ti alaga igbimọ naa, Regina Akume buwọ lu, o sọ pe awọn nilo lati ṣe iwadii kikun, lati mọ ọna ti wọn le gba labẹ ofin lati fofin de awọn ọti pẹlẹbẹ ati ọti inu igo kekere naa.
Ṣé lóòótọ́ ni pé Dapo Abiodun ń ṣètò 'palliative' N10,000 lójú òpó ayélujára f'aráàlú?
Ọkan lara awọn oluranwọ Gominba lo kede ikilọ fun araalu lori iroyin yi to si ni ijọba Dapo Abiodun ko pin owo ọfẹ lori ayelujara
E ṣe sùúrù fún Tinubu, ọrọ̀ ajé Naijiria ti di òkú kó tó gbàjọba lọ́wọ́ Buhari – Fayose
Fayose lo sọ ọrọ naa ninu ifọrọwerọ kan pẹlu ileeṣẹ iroyin Channels, nibi to ti ni ọrọ aje Naijiria ti di oku ki Tinubu to gba ijọba.
Ẹgbẹ́ òṣìṣẹ́ NLC, ẹ tún èrò yín pa lórí ìwọ́de tí ẹ fẹ́ ṣe - Mínísítà ètò ìdájọ́
Ninu lẹta ti agbejọro agba naa kọ ranṣẹ si ẹgbẹ oṣiṣẹ NLC laipẹ yii lo ti sọ pe iwe aṣẹ kan wa nilẹ to tako igbeṣẹ ẹgbẹ naa lati jade ṣe iwọde lasiko yii.
Hakeem Effect: Idán inú eré sinimá ti gbàràdá ní Nàìjíríà
Opọ arugbo ni Hakeem ti sọ di ọmọge bẹẹ lo ti sọ ẹya ara awọn eeyan di nkan mii laarin ọdun mẹrinla ti oun ti n ṣe e.
Báyìí ni ìjàmbá ọkọ̀ bàálú tó pa Wigwe, ìyàwó àti ọmọ ṣe wáyé
Ọdun 1966 ni wọn bi Herbert Onyewumbu Wigwe, niluu Port Harcourt, nipinlẹ Rivers.
Tinubu, kéde ìlú ó fararọ ní Nàìjíríà lórí ọ̀wọ́ngógó tó gbòde - Àjọ ọmọ lẹ́yìn Krístì PFN
Aarẹ ajọ naa. Bíṣọọbu Wale Oke lo sọ eyi lasiko ipade apapọ ọmọ lẹyin Kristi ti ajọ CPFN/PFN níbi tí wọn ti sọrọ nipa gbogbo ìnira tí ilu n la kọja lasiko yii
Ìdí rèé tí àjọ ECOWAS fi gbẹ́sẹ̀ kúrò lórí òfin tó fi de Niger, Mali, Burkina Faso àti Guinea
Gege ti wọn gbe lori awọn mẹrin yii tẹlẹ ni pe awọn orileede yooku ko nii ba wọn dowopọ yala lẹka eto irin ajo, okoowo tabi eto ọrọ aje.
Gowon ní kí àwọn ọmọ Nàíjíríà ṣe sùúrù fún Ààrẹ Tinubu
Iṣoro ọwọngogo ounjẹ yii fa iwọde ni awọn ipinlẹ kan lorilẹede Naijiria, ipinlẹ Oyo, Niger ati Eko.
Kò sí ohun tó lè dá ìfẹ̀hónúhàn wa dúró – NLC sọ fún àjọ ọ̀tẹlẹ̀múyẹ́
Ṣaaju asiko yii ni ajọ ọtẹlẹmuyẹ, DSS ti rọ ẹgbẹ NLC lati so ifẹhonuhan ti wọn fẹẹ ṣe rọ fungba diẹ, pẹlu erongba lati gba alaafia laaye.
Iléẹjọ́ ní kí wọ́n lọ yẹgi fún Pásítọ̀,èèyàn márùn-ún míì to fọ báńkì méjì
Ile ẹjọ gbe idajọ kalẹ pe wọn jẹbi ẹsun idigunjale nigba ti wọn kọlu awọn banki kan to wa ni Akure ati Idanre lọdun 2011.
Ìròyìn Pàtàkì
Kọ́milẹ́kọ̀ọ́
Móríwú
Ìwádìí kíkún lóríi kókó ìròyìn
Komla Dumor Award 2024: BBC tún ṣetán láti wá ìràwọ̀ akọ̀ròyìn míì ní Africa
Ẹni to ba gbegba oroke ninu idije yii yoo lo oṣu mẹfa ni ile igbohunsafẹfẹ BBC to wa niluu London ti yoo si ba awọn oniroyin to moye ju lagbaye ṣiṣẹ pọ
Àwọn wo ló maa jẹ ànfààní N25,000 tí ìjọba àpapọ̀ fẹ́ẹ́ pín fáwọn aráàlú?
Bi awọn araalu ṣe n pariwo pe ilu ko fararọ, Aarẹ Bọla Tinubu ti sọ pe niṣe ni wọn yoo bẹrẹ sii fi awọn owo naa ranṣẹ sinu apo ile ifowopamọ awọn alaini ati awọn to ku diẹ kato fun.
Ọkùnrin kan gbé iléeṣẹ́ tẹ́tẹ́ re ilé ẹjọ́ lẹ́yìn tí wọ́n ní àṣìṣe ni N510bn tó jẹ
Ọkunrin naa ti orukọ rẹ n jẹ John Cheeks sọ pe niṣe ni pajapaja mu oun lara nigba ti oun ri pe tikẹẹti oun jẹ owo gọbọi naa ni oṣu Kinni ọdun 2023.
A kò ní padà sẹ́yìn lórí ìgbésẹ̀ àti mú àyípadà rere bá Nàìjíríà - Tinubu
Aarẹ Bola Tinubu lọ sọrọ yii lasiko to n gba ikọ ajọ Corporate Council on Africa (CCA) ti alakoso agba wọn, Florizelle Liser lewaju fun lalejo nile agbara tiliu Abuja lalejo l’Ọjọbọ, ọsẹ yii.
Ìyàwó mi Ropo ni wọ́n lò láti mú mi ní Benin Republic - Sunday Igboho
Nibi ayẹyẹ isinku iya rẹ, to waye n'ilu Igboho nipinlẹ Oyo, l'Ọjọ́bọ, ọjọ kẹtalelogun, oṣu Keji, ni Igboho ti tu kẹ̀kẹ́ ọrọ silẹ.
Wo àwọn àwòrán tó jẹ ojú ni gbèsè pẹ̀lú àwọn èèkàn tó wá síbi òkú Iya Sunday Igboho
Sunday Igboho ni oun ko ni bu Aarẹ Bola Tinubu lori ọwọngogo to gbode nitori pe aarẹ tuntun to n bẹ lori aleefa lọwọlọwọ bayii kọ lo ba Naijiria jẹ.
Laide Bakare di amúgbálẹ́gbẹ̀ẹ́ fọ́rọ̀ àṣà fún Gómìnà Adeleke, aáwọ̀ bẹ̀rẹ̀ láàrin òun àti Portable
Laide Bakare kede ipo tuntun yii lori opo ayelujara rẹ pẹlu aworan oun ati Gomina Ademola Adeleke.
Wo ọ̀nà tí ìjọba fẹ́ gbà láti gbọn ìṣẹ́ dànù lára ọmọ Nàìjíríà
Ọjọ Ẹti to kọja ni Minisita feto iṣuna, ẹni to tun jẹ minisita alabojuto fun eto ọrọ aje Naijiria sọrọ naa.
Olùsọ́ tó ṣe àpérò àyájọ́ olólùfẹ́ léti òkun l'Eko, bá omi lọ
Oloogbe naa lo lewaju awọn ọdọ ile ijọsin Celestial Church of Christ, ti ẹka Gbagada lọ si eti okun Avista lọjọ kẹtadinlogun oṣu keji ọdun 2024.
Irọ́ ni pé a kọlu àwọn akẹ́kọ̀ọ́ KWASU l'Ọjọ́bọ, bí ọ̀rọ̀ ṣe rí rèé...
Ẹsun to nii ṣe pẹlu jibiti ẹrọ ayelujara ni EFCC fi kan wọn awọn akẹkọọ tọwọ tẹ naa.